Sáàmù 19:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohùn wọn jáde lọ sí gbogbo orílẹ̀ ayéọ̀rọ̀ wọn títí dé òpin ilẹ̀ ayé,ó ti kọ́ àgọ́ fún oòrùn nínú àwọn ọ̀run.

Sáàmù 19

Sáàmù 19:1-10