Sáàmù 145:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn yóò máa sọ ìyìn ọlá ńlá Rẹ tí ó lógo,èmi yóò máa ṣe àṣàrò nínú iṣẹ́ ìyanu Rẹ.

Sáàmù 145

Sáàmù 145:1-13