Sáàmù 145:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn yóò sọ iṣẹ́ agbára Rẹ tí ó ní ẹ̀rùèmi yóò kéde iṣẹ́ ńlá Rẹ̀.

Sáàmù 145

Sáàmù 145:5-10