Sáàmù 145:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìran kan yóò máa yin iṣẹ́ Rẹ dé ìran mìíràn;wọn yóò máa sọ iṣẹ́ agbára Rẹ

Sáàmù 145

Sáàmù 145:1-8