Sáàmù 145:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Títóbi ni Olúwa. Òun sì ni ó yẹ láti fi ìyìn fún púpọ̀púpọ̀:kò sí ẹni tí ó lè wọn títóbi Rẹ̀.

Sáàmù 145

Sáàmù 145:1-7