Sáàmù 144:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìyìn sí Olúwa àpáta mi,ẹni tí ó kọ́ ọwọ́ mi fún ogun,àti ìka mi fún ìjà.

Sáàmù 144

Sáàmù 144:1-10