Sáàmù 144:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun ni Ọlọ́run ìfẹ́ mi àti odi alágbára mi,ibi gíga mi àti olùgbàlà mi, asà mi,ẹni tí èmi gbẹ́kẹ̀lé,ẹni tí ó tẹ́rí àwọn ènìyàn ba lábẹ́ mi

Sáàmù 144

Sáàmù 144:1-12