Sáàmù 143:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú ìfẹ́ Rẹ tí kì í kùnà, ké àwọn ọ̀ta mi kúrò,run gbogbo àwọn ọ̀tá mi,nítorí èmi ni ìránṣẹ́ Rẹ.

Sáàmù 143

Sáàmù 143:2-12