Sáàmù 136:24-26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

24. Ó sì dá wa ní ìdè lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wa;nítorí tí àánú Rẹ̀ dúró láéláé.

25. Ẹni tí ó fi oúnjẹ fún àwọn ẹ̀dá gbogbonítorí tí àánú Rẹ̀ dúró láéláé.

26. Ẹ fi ọpẹ́ fún Ọlọ́run ọ̀run;nítorí tí àánú Rẹ̀ dúró láéláé.

Sáàmù 136