Sáàmù 136:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì dá wa ní ìdè lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wa;nítorí tí àánú Rẹ̀ dúró láéláé.

Sáàmù 136

Sáàmù 136:15-26