Sáàmù 137:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ẹ̀bá odò Bábílónì, níbẹ̀ ní àwa gbé jókòóàwa sì sunkún nígbà tí àwa rántí Síónì.

Sáàmù 137

Sáàmù 137:1-2