Sáàmù 134:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ gbé ọwọ́ yín sókè sí ibi mímọ́,kí ẹsì fi ìbùkún fún Olúwa.

Sáàmù 134

Sáàmù 134:1-3