Sáàmù 134:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ kíyèsí i, ẹ fi ìbùkún fún Olúwa,gbogbo ẹ̀yin ìránṣẹ́ Olúwa,tí ó dúró ní ilé Olúwa ní òru.

Sáàmù 134

Sáàmù 134:1-3