Sáàmù 127:3-5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

3. Kíyèsí i, àwọn ọmọ ni ìní Olúwa:ọmọ inú sì ni èrè Rẹ̀.

4. Bí ọfà ti rí ní ọwọ́ alágbára,bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ èwe

5. Ìbùkún ni fún ọkùnrin náà tí ààbò Rẹ̀ kún fún wọn;ojú kì yóò tì wọ́n,ṣùgbọ́n wọn yóò sẹ́gun àwọn ọ̀ta ní ẹnu ọ̀nà.

Sáàmù 127