Sáàmù 126:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni tí ń fi ẹkún rìn lọ,tí ó sì gbé irúgbìn lọ́wọ́,lóòtọ́, yóò fi ayọ̀ padà wá,yóò sì ru ìtí Rẹ̀.

Sáàmù 126

Sáàmù 126:1-6