Sáàmù 127:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbùkún ni fún ọkùnrin náà tí ààbò Rẹ̀ kún fún wọn;ojú kì yóò tì wọ́n,ṣùgbọ́n wọn yóò sẹ́gun àwọn ọ̀ta ní ẹnu ọ̀nà.

Sáàmù 127

Sáàmù 127:1-5