Sáàmù 126:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Nígbà tí Olúwa mú ìkòlọ Síónì padà,àwa dàbí ẹni tí o ń lá àlá.

2. Nígbà náà ni ẹnu wa kún fún ẹ̀rín,àti ahọ́n wa kọ orin;nígbà náà ni wọ́n wí nínú àwọn aláìkọlà pé, Olúwa ṣe ohun ńlá fún wọn.

3. Olúwa ṣe ohun ńlá fún wa;nítorí náà àwa ń yọ̀.

Sáàmù 126