Nígbà náà ni ẹnu wa kún fún ẹ̀rín,àti ahọ́n wa kọ orin;nígbà náà ni wọ́n wí nínú àwọn aláìkọlà pé, Olúwa ṣe ohun ńlá fún wọn.