Sáàmù 125:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó ṣe ti irú àwọn tí wọn yà sí ipa ọ̀nà wíwọ́ wọn; Olúwa yóò jẹ́ kí wọn lọ pẹ̀lú àwọn oníṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀.Ṣùgbọ́n àlàáfíà yóò wà lórí Ísírẹ́lì.

Sáàmù 125

Sáàmù 125:1-5