Sáàmù 101:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni tí o bá ń ṣe ẹ̀tàn, kì yóò gbé ilé mi,kò sí ẹni tí ń ṣèké ti yóò dúró ní iwájú mi.

Sáàmù 101

Sáàmù 101:2-8