Ojú mi yóò wà lára àwọn olóòtọ́ lórí ilẹ̀,kí wọn kí ó le máa bá mi gbé;ẹni tí o bá ń rìn ọ̀nà pípéòun ni yóò máa sìn mí.