Sáàmù 101:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ojojúmọ́ ní èmi yóò wá máa pa lẹ́nu mọgbogbo àwọn ènìyàn búburú ilẹ̀ náà;èmi yóò gé àwọn olùṣe búburúkúrò ní ìlú Olúwa.

Sáàmù 101

Sáàmù 101:1-8