Sáàmù 10:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó lúgọ ní bùba nítòsí ìletò;ó gọ níbi ìkọ̀kọ̀ láti pa aláìṣẹ̀,ojú Rẹ̀ ń ṣọ́ àwọn talákà ní ìkọ̀kọ̀.

Sáàmù 10

Sáàmù 10:1-11