Sáàmù 10:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹnu Rẹ̀ kún fún ẹ̀gàn àti irọ́ àti ìtànjẹ;wàhálà àti ohun búburú wa lábẹ́ ahọ́n Rẹ̀.

Sáàmù 10

Sáàmù 10:3-12