Òwe 3:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe wí fún aládùúgbò rẹ pé,“Padà wá nígbà tó ṣe díẹ̀; ó fún ọ lọ́lá”nígbà tí o ní i pẹ̀lú rẹ nísinsin yìí.

Òwe 3

Òwe 3:19-33