Òwe 3:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe fa ọwọ́ ire sẹ́yìn kúrò lọ́dọ̀ àwọn tí ó tọ́ sí,nígbà tí ó bá wà ní ìkápá rẹ láti ṣe ohun kan.

Òwe 3

Òwe 3:20-35