Òwe 3:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe pète ohun búburú fún aládùúgbò rẹ,ti o gbé nítòsí rẹ, tí ó sì fọkàn tán ọ.

Òwe 3

Òwe 3:22-35