Òwe 21:29-31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

29. Ènìyàn búburú mú ojú ara rẹ̀ le:ṣùgbọ́n ẹni ìdúró-ṣinṣin ni ó ń mú ọ̀nà rẹ̀ tọ́.

30. Kò sí ọgbọ́n, kò sí ìmòye,tàbí ìmọ̀ràn tí ó le mókè níwájú Olúwa.

31. A ń múra ẹṣin sílẹ̀ de ọjọ́ ogun:ṣùgbọ́n ìṣẹ́gun jẹ́ ti Olúwa.

Òwe 21