Òwe 22:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yíyan orúkọ rere ṣàn ju púpọ̀ ọrọ̀ lọ,àti ojúrere dára ju fàdákà àti wúrà lọ.

Òwe 22

Òwe 22:1-5