Òwe 20:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìgbájú ìgbámú àti ìfarapa máa ń mú ibi lọ,pàsán sì máa ń ṣe àfọ̀mọ́ ibi ìkọ̀kọ̀ inú.

Òwe 20

Òwe 20:25-30