Òwe 21:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ọkàn ọba ń bẹ lọ́wọ́ Olúwa;a máa darí rẹ̀ lọ ibi tí ó fẹ́ bí ipa omi.

2. Gbogbo ọ̀nà ènìyàn dàbí i pé ó dára lójú rẹ̀ṣùgbọ́n, Olúwa ló ń díwọ̀n ọkàn.

Òwe 21