Orin Sólómónì 5:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀yin ọmọbìnrin Jérúsálẹ́mù, mo bẹ̀ yínbí ẹ̀yin bá rí olùfẹ́ mi,kí ni ẹ̀yin yóò wí fún un?Ẹ wí fún un pé àìṣàn ìfẹ́ ń ṣe mi.

Orin Sólómónì 5

Orin Sólómónì 5:1-14