Orin Sólómónì 5:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ni olùfẹ́ rẹ fi dára ju àwọn tó kù lọÌwọ arẹwà jùlọ láàárin àwọn obìnrin?Kí ni olùfẹ́ rẹ fi dára ju àwọn tó kù lọtí ìwọ fi ń rọ̀ wá bẹ́ẹ̀?

Orin Sólómónì 5

Orin Sólómónì 5:1-16