Orin Sólómónì 3:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní orí ìbùsùn mi ní òrumo wá ẹni tí ọkàn mí fẹ́;mo wá a, ṣùgbọ́n èmi kò rí i.

Orin Sólómónì 3

Orin Sólómónì 3:1-4