Orin Sólómónì 3:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò dìde nísinsin yìí, èmi yóò sì rìn lọ káàkiri ìlú,ní àwọn òpópónà àti ní àwọn gbangba òde;Èmi yóò wá ẹni tí ọkàn mi fẹ́.Bẹ́ẹ̀ ni mo wá a ṣùgbọ́n èmi kò rí i.

Orin Sólómónì 3

Orin Sólómónì 3:1-6