Nehemáyà 6:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n bẹ̀ẹ́ ní ọ̀wẹ̀ láti dẹ́rù bà mí nítorí kí èmi lè dẹ́ṣẹ̀ nípa ṣíṣe èyí, kí wọn lè bà mí lórúkọ jẹ́, kí n sì di ẹni ẹ̀gàn.

Nehemáyà 6

Nehemáyà 6:4-19