Nehemáyà 6:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A! Ọlọ́run mi, rántí Tòbáyà àti Ṣáńbálátì, nítorí ohun tí wọ́n ti ṣe; kí o sì tún rántí Nóádáyà wòlíì obìnrin àti àwọn wòlíì tókù tí wọ́n ń gbérò láti dẹ́rù bà mí.

Nehemáyà 6

Nehemáyà 6:8-19