Nehemáyà 6:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi wòye pé Ọlọ́run kò rán-an, ṣùgbọ́n ó sọ àṣọtẹ́lẹ̀ sí mi nítorí Tòbáyà àti Sáńbálátì ti bẹ̀ẹ́ ní ọ̀wẹ̀.

Nehemáyà 6

Nehemáyà 6:4-19