Mátíù 25:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ní àsìkò tí wọ́n lọ ra epo tiwọn, ni ọkọ ìyàwó dé. Àwọn wúńdíá tí ó múra tán bá a wọlé sí ibi àṣè ìgbéyàwó, lẹ̀yìn náà, a sì ti ìlẹ̀kùn.

Mátíù 25

Mátíù 25:9-11