Mátíù 25:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ní ìkẹyìn ni àwọn wúńdíá márùn-ún ìyókù dé, wọ́n ń wí pé, ‘olúwa, olúwa, sílẹ̀kùn fún wa.’

Mátíù 25

Mátíù 25:6-14