Mátíù 14:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nítorí Jòhánù onítẹ̀bọmi ti sọ fún Hẹ́rọ́dù pé, “Kò yẹ fún ọ láti fẹ́ obìnrin náà.”

Mátíù 14

Mátíù 14:1-7