Mátíù 14:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísìnsin yìí Hẹ́rọ́dù ti mú Jòhánù, ó fi ẹ̀wọ̀n dè é, ó sì fi sínú túbú, nítorí Hẹ́rọ́díà aya Fílípì arákùnrin rẹ̀,

Mátíù 14

Mátíù 14:1-7