Mátíù 14:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Hẹ́rọ́dù fẹ pa Jòhánù, ṣùgbọ́n ó bẹ̀rù àwọn ènìyàn nítorí gbogbo ènìyàn gbàgbọ́ pé wòlíì ni.

Mátíù 14

Mátíù 14:4-14