Lúùkù 6:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ ìsinmi kan, Jésù ń kọjá láàrin oko ọkà; àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ sì ń ya ìpẹ́ ọkà, wọ́n sì ń jẹ ẹ́.

Lúùkù 6

Lúùkù 6:1-3