Lúùkù 6:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn kan nínú àwọn Farisí sì wí fún wọn pé, “Èéṣe tí ẹ̀yin fi ń ṣe èyí tí kò yẹ láti ṣe ní ọjọ́ ìsinmi?”

Lúùkù 6

Lúùkù 6:1-12