Lúùkù 5:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò sì ẹni tí yóò fẹ́ láti mu wáìnì tuntun lẹ́yìn tí ó bá ti mu ogbólógbò tán, nítorí yóò wí pé ‘èyí tí ó jẹ́ ògbólógbò dára jù.’ ”

Lúùkù 5

Lúùkù 5:36-39