Lúùkù 19:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ń fẹ́ láti rí ẹni tí Jésù jẹ́: kò sì lè rí i, nítrorí ọ̀pọ̀ ènìyàn, àti nítorí tí òun jẹ́ ènìyàn kúkúrú.

Lúùkù 19

Lúùkù 19:1-4