Lúùkù 19:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sì kíyèsí i, ọkùnrin kan wà tí a ń pè ní Sákéù, ó sì jẹ́ olórí agbowó òde kan, ó sì jẹ́ ọlọ́rọ̀.

Lúùkù 19

Lúùkù 19:1-3