Lúùkù 15:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ó sì wí fún un pé, ‘Ọmọ, nígbà gbogbo ni ìwọ ń bẹ lọ́dọ̀ mi, ohun gbogbo tí mo sì ní, tìrẹ ni.

Lúùkù 15

Lúùkù 15:21-32