Lúùkù 15:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó yẹ kí a ṣe àríyá kí a sì yọ̀: nítorí àbúrò rẹ yìí ti kú, ó sì tún yè; ó ti nù, a sì rí i.’ ”

Lúùkù 15

Lúùkù 15:28-32